Asa Iba Lyrics

Iba feledua - by Asa

Everyday, so God...
Bacause of you. i dey live, i dey breath, i dey eat
so, I wanna have some talk with you

Orun, silekun i wanna have some talk, [with] you o (2xe)

Nitori re mose n lola
Nitori re mose n s'oge
Nitori re mose n ra moto

Mowole,M'oboluwa mi soro

Nitori re mose wa laye
Nitori re mose n woso sara
Nitori re moji l'owuro
Mow'aye mi lode ye

A o, Aa a o o ibafeledu'a
A o, Aa a o o
mowole , M'obolowa mi soro

Nitori re mose n gbo iroyin ayo
Lais'owo laisi nkankan
Iya oni, layoola o
B'oluwa tiwi, be naa lori

Jiji moji lowuro
Moji si inu ipese re
Ayo at'alafia ye ye

O, o o oni pe ki n ma se beru

A o, Aa a o o ibafeledu'a
A o, Aa a o o
mowole , M'obolowa mi soro

Melo la fe so
Melo lo si n bowa
Melo la fe so, eh
Melo lo si n bowa

Nitori re mose n sa ko, everyday, eh eh
Nitori re mojijo lese mi, oh oh oh, oh oh
Ninu iponju, Ninu idamu,
b'ebi ba n p'ona
mawole, maboluwa mi soro

B'emi o le yan
Baye ba foju dimi
B'emi o le ni
Mawole, maboluwa mi soro

A o, Aa a o o ibafeledu'a
A o, Aa a o o
mowole , M'obolowa mi soro

Ninu iponju, Ninu idamu,
b'ebi ba n p'ona
mawole, maboluwa mi soro
Mioni foju sunkun mo o
Aye loja, oh oh...Orun..Orunile
And thats fine by me....eh eh...
Oh..ye ye...bring it down...oh oh..

See also:

82
82.72
Amarillo vegetariana Lyrics
Andrea Alvarez Dormís? Lyrics